Sáàmù 137:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ibẹ̀ ni àwọn tó mú wa lẹ́rú ti ní ká kọrin,+Àwọn tó ń fi wá ṣẹ̀sín fẹ́ ká dá àwọn lára yá, wọ́n ní: “Ẹ kọ ọ̀kan lára àwọn orin Síónì fún wa.” Jeremáyà 50:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jẹ́ àwọn àgùntàn tó tú ká.+ Àwọn kìnnìún ti fọ́n wọn ká.+ Ọba Ásíríà ló kọ́kọ́ jẹ wọ́n;+ lẹ́yìn náà, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì jẹ egungun wọn.+
3 Ibẹ̀ ni àwọn tó mú wa lẹ́rú ti ní ká kọrin,+Àwọn tó ń fi wá ṣẹ̀sín fẹ́ ká dá àwọn lára yá, wọ́n ní: “Ẹ kọ ọ̀kan lára àwọn orin Síónì fún wa.”
17 “Àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jẹ́ àwọn àgùntàn tó tú ká.+ Àwọn kìnnìún ti fọ́n wọn ká.+ Ọba Ásíríà ló kọ́kọ́ jẹ wọ́n;+ lẹ́yìn náà, Nebukadinésárì* ọba Bábílónì jẹ egungun wọn.+