Òwe 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹbọ ẹni burúkú jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+Àmọ́ àdúrà àwọn adúróṣinṣin máa ń múnú Rẹ̀ dùn.+ 1 Pétérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+
12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+