ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 9:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Lẹ́yìn náà, mo mú ohun tí ẹ ṣe tó mú kí ẹ dẹ́ṣẹ̀, ìyẹn ọmọ màlúù náà,+ mo sì dáná sun ún; mo fọ́ ọ túútúú, mo sì lọ̀ ọ́ kúnná títí ó fi di lẹ́búlẹ́bú bí eruku, mo sì dà á sínú odò tó ń ṣàn látorí òkè náà.+

      22 “Bákan náà, ẹ tún múnú bí Jèhófà ní Tábérà,+ Másà+ àti ní Kiburoti-hátááfà.+

  • Sáàmù 95:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ẹ má ṣe mú kí ọkàn yín le bí ẹ ṣe ṣe ní Mẹ́ríbà,*+

      Bíi ti ọjọ́ Másà* ní aginjù,+

  • Hébérù 3:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí, àwọn wo ló gbọ́, síbẹ̀ tí wọ́n mú un bínú gidigidi? Ní tòótọ́, ṣebí gbogbo àwọn tí Mósè kó jáde ní Íjíbítì ni?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́