25Ní ọdún kẹsàn-án ìjọba Sedekáyà, ní oṣù kẹwàá, ní ọjọ́ kẹwàá oṣù náà, Nebukadinésárì+ ọba Bábílónì dé pẹ̀lú gbogbo ọmọ ogun rẹ̀ láti gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+ Ó dó tì í, ó mọ òkìtì yí i ká,+
32Lẹ́yìn tí Hẹsikáyà ti fi òtítọ́ ṣe àwọn nǹkan yìí,+ Senakérúbù ọba Ásíríà wá, ó sì ya wọ Júdà. Ó dó ti àwọn ìlú olódi, ó fẹ́ wọlé kí ó sì gbà wọ́n.+