-
2 Sámúẹ́lì 10:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tó yá, àwọn ọmọ Ámónì rí i pé àwọn ti di ẹni ìkórìíra lójú Dáfídì, torí náà àwọn ọmọ Ámónì ránṣẹ́ sí àwọn ará Síríà tó wà ní Bẹti-réhóbù+ àti àwọn ará Síríà tó wà ní Sóbà,+ wọ́n sì háyà ọ̀kẹ́ kan (20,000) àwọn ọmọ ogun tó ń fẹsẹ̀ rìn lọ́dọ̀ wọn; àti lọ́dọ̀ ọba Máákà,+ ẹgbẹ̀rún kan (1,000) ọkùnrin; àti láti Íṣítóbù,* ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ọkùnrin.+
-
-
Àìsáyà 7:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ìròyìn dé ilé Dáfídì pé: “Síríà ti lẹ̀dí àpò pọ̀ mọ́ Éfúrémù.”
Jìnnìjìnnì bá ọkàn Áhásì àti ti àwọn èèyàn rẹ̀, wọ́n ń gbọ̀n pẹ̀pẹ̀ bí àwọn igi inú igbó tí atẹ́gùn ń fẹ́ lù.
-
-
Àìsáyà 7:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Torí Síríà pẹ̀lú Éfúrémù àti ọmọ Remaláyà ti gbìmọ̀ ìkà sí ọ, wọ́n ń sọ pé:
-