- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 8:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        16 ‘Láti ọjọ́ tí mo ti mú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì jáde kúrò ní Íjíbítì, mi ò yan ìlú kankan nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì tí màá kọ́ ilé sí fún orúkọ mi, kí ó lè máa wà níbẹ̀,+ ṣùgbọ́n mo ti yan Dáfídì láti ṣe olórí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.’ 
 
-