- 
	                        
            
            Sáàmù 33:13-15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        13 Jèhófà bojú wolẹ̀ láti ọ̀run; Ó ń rí gbogbo ọmọ èèyàn.+ 14 Láti ibi tó ń gbé, Ó ń wo gbogbo àwọn tó ń gbé ayé. 
 
- 
                                        
13 Jèhófà bojú wolẹ̀ láti ọ̀run;
Ó ń rí gbogbo ọmọ èèyàn.+
14 Láti ibi tó ń gbé,
Ó ń wo gbogbo àwọn tó ń gbé ayé.