Diutarónómì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+ Jóṣúà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọba ilẹ̀ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun nìyí, tí wọ́n gba ilẹ̀ wọn lápá ìlà oòrùn Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì+ dé Òkè Hámónì+ àti gbogbo Árábà lápá ìlà oòrùn:+
8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+
12 Àwọn ọba ilẹ̀ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun nìyí, tí wọ́n gba ilẹ̀ wọn lápá ìlà oòrùn Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì+ dé Òkè Hámónì+ àti gbogbo Árábà lápá ìlà oòrùn:+