Nọ́ńbà 17:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá sọ fún Mósè pé: “A máa kú báyìí, ó dájú pé a máa ṣègbé, gbogbo wa la máa ṣègbé! 13 Kódà, ẹnikẹ́ni tó bá sún mọ́ àgọ́ ìjọsìn Jèhófà máa kú!+ Ṣé bí gbogbo wa ṣe máa kú nìyẹn?”+ Diutarónómì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.
12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá sọ fún Mósè pé: “A máa kú báyìí, ó dájú pé a máa ṣègbé, gbogbo wa la máa ṣègbé! 13 Kódà, ẹnikẹ́ni tó bá sún mọ́ àgọ́ ìjọsìn Jèhófà máa kú!+ Ṣé bí gbogbo wa ṣe máa kú nìyẹn?”+
22 Torí ìbínú mi ti mú kí iná+ sọ,Ó sì máa jó wọnú Isà Òkú,*+Ó máa jó ayé àti èso rẹ̀ run,Iná á sì ran ìpìlẹ̀ àwọn òkè.