Sáàmù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+ Òwe 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ Jèhófà jẹ́ ilé gogoro tó lágbára.+ Olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ààbò.*+
2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+