- 
	                        
            
            1 Kíróníkà 25:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Gbogbo wọn wà lábẹ́ ìdarí bàbá wọn láti máa kọrin ní ilé Jèhófà pẹ̀lú síńbálì, àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti háàpù+ fún iṣẹ́ ìsìn ilé Ọlọ́run tòótọ́. Àwọn tó wà lábẹ́ àṣẹ ọba ni Ásáfù, Jédútúnì àti Hémánì. 
 
-