Sáàmù 25:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni rere àti adúróṣinṣin ni Jèhófà.+ Ìdí nìyẹn tó fi ń kọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀nà tó yẹ kí wọ́n tọ̀.+ Àìsáyà 28:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Torí Ó ń kọ́ ọ* ní ọ̀nà tó tọ́;Ọlọ́run rẹ̀ ń fún un ní ìtọ́ni.+ Jòhánù 6:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 A kọ ọ́ sínú àwọn Wòlíì pé: ‘Jèhófà* máa kọ́ gbogbo wọn.’+ Gbogbo ẹni tó bá ti gbọ́ ti Baba, tó sì ti kẹ́kọ̀ọ́ ń wá sọ́dọ̀ mi.
8 Ẹni rere àti adúróṣinṣin ni Jèhófà.+ Ìdí nìyẹn tó fi ń kọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọ̀nà tó yẹ kí wọ́n tọ̀.+
45 A kọ ọ́ sínú àwọn Wòlíì pé: ‘Jèhófà* máa kọ́ gbogbo wọn.’+ Gbogbo ẹni tó bá ti gbọ́ ti Baba, tó sì ti kẹ́kọ̀ọ́ ń wá sọ́dọ̀ mi.