Sáàmù 25:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ṣọ́ ẹ̀mí* mi, kí o sì gbà mí sílẹ̀.+ Má ṣe jẹ́ kí ojú tì mí, nítorí ìwọ ni mo fi ṣe ibi ààbò mi.