Sáàmù 17:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Dáàbò bò mí bí ọmọlójú rẹ;+Fi mí pa mọ́ sábẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.+ Sáàmù 121:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà yóò máa ṣọ́ ọ kí jàǹbá kankan má ṣe ọ́.+ Yóò máa ṣọ́ ẹ̀mí* rẹ.+