- 
	                        
            
            2 Kíróníkà 29:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        27 Nígbà náà, Hẹsikáyà pàṣẹ pé kí wọ́n rú ẹbọ sísun náà lórí pẹpẹ.+ Nígbà tí ẹbọ sísun náà bẹ̀rẹ̀, orin Jèhófà bẹ̀rẹ̀, kàkàkí sì bẹ̀rẹ̀ sí í dún, wọ́n ń tẹ̀ lé àwọn ohun ìkọrin Dáfídì ọba Ísírẹ́lì. 
 
-