Sáàmù 22:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Nítorí kò gbójú fo ìyà tó ń jẹ ẹni tí ara ń ni, kò sì ṣàìka ìpọ́njú rẹ̀ sí;+Kò gbé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún un.+ Nígbà tó ké pè é fún ìrànlọ́wọ́, ó gbọ́.+
24 Nítorí kò gbójú fo ìyà tó ń jẹ ẹni tí ara ń ni, kò sì ṣàìka ìpọ́njú rẹ̀ sí;+Kò gbé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún un.+ Nígbà tó ké pè é fún ìrànlọ́wọ́, ó gbọ́.+