ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 8:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Nígbà tí mo rí ọ̀run rẹ, àwọn iṣẹ́ ìka rẹ,

      Òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀ tí o ti ṣètò sílẹ̀,+

  • Àìsáyà 48:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Ọwọ́ mi ni mo fi fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀,+

      Ọwọ́ ọ̀tún mi ni mo sì fi na ọ̀run.+

      Tí mo bá pè wọ́n, wọ́n jọ máa dìde.

  • Hébérù 1:10-12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àti pé: “Ní ìbẹ̀rẹ̀, Olúwa, o fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀, ọ̀run sì jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. 11 Wọ́n á ṣègbé, àmọ́ ìwọ á máa wà nìṣó; gbogbo wọn á sì gbó bí aṣọ, 12 o máa ká wọn jọ bí aṣọ àwọ̀lékè, a sì máa pààrọ̀ wọn bí aṣọ. Àmọ́ ìwọ ò yí pa dà, àwọn ọdún rẹ ò sì ní dópin láé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́