Nehemáyà 9:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+
31 Nínú àánú ńlá rẹ, o ò pa wọ́n run,+ o ò sì fi wọ́n sílẹ̀, nítorí Ọlọ́run tó ń gba tẹni rò* àti aláàánú ni ọ́.+