-
Jẹ́nẹ́sísì 1:29, 30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ọlọ́run sì sọ pé: “Mo fún yín ní gbogbo ewéko ní gbogbo ayé, àwọn tó ní irúgbìn àti gbogbo igi eléso tó ní irúgbìn. Kí wọ́n jẹ́ oúnjẹ fún yín.+ 30 Mo sì fi gbogbo ewéko tútù ṣe oúnjẹ fún gbogbo ẹran inú igbó àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run àti gbogbo ohun abẹ̀mí* tó ń rìn lórí ilẹ̀.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
-