Sáàmù 11:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ń ṣàyẹ̀wò olódodo àti ẹni burúkú;+Ó* kórìíra ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ìwà ipá.+ Sáàmù 16:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá yin Jèhófà, ẹni tó fún mi ní ìmọ̀ràn.+ Kódà láàárín òru, èrò inú mi* ń tọ́ mi sọ́nà.+ 1 Kọ́ríńtì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí mi ò rí nǹkan tó burú nínú ohun tí mo ṣe. Àmọ́, èyí kò túmọ̀ sí pé mo jẹ́ olódodo; ẹni tó ń wádìí mi wò ni Jèhófà.*+
4 Nítorí mi ò rí nǹkan tó burú nínú ohun tí mo ṣe. Àmọ́, èyí kò túmọ̀ sí pé mo jẹ́ olódodo; ẹni tó ń wádìí mi wò ni Jèhófà.*+