Sáàmù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O ti ṣàyẹ̀wò ọkàn mi, o ti bẹ̀ mí wò ní òru;+O ti yọ́ mi mọ́;+Wàá rí i pé mi ò ní èrò ibi kankan lọ́kàn,Ẹnu mi kò sì dẹ́ṣẹ̀. Sáàmù 26:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Yẹ̀ mí wò, Jèhófà, kí o sì dán mi wò;Yọ́ èrò inú mi* àti ọkàn mi mọ́.+
3 O ti ṣàyẹ̀wò ọkàn mi, o ti bẹ̀ mí wò ní òru;+O ti yọ́ mi mọ́;+Wàá rí i pé mi ò ní èrò ibi kankan lọ́kàn,Ẹnu mi kò sì dẹ́ṣẹ̀.