Ẹ́kísódù 12:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àwọn ará Íjíbítì wá ń rọ àwọn èèyàn náà pé kí wọ́n tètè kúrò ní ilẹ̀ náà.+ Wọ́n sọ pé, “Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, gbogbo wa la máa kú!”+
33 Àwọn ará Íjíbítì wá ń rọ àwọn èèyàn náà pé kí wọ́n tètè kúrò ní ilẹ̀ náà.+ Wọ́n sọ pé, “Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, gbogbo wa la máa kú!”+