- 
	                        
            
            Jeremáyà 15:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        21 “Màá sì gbà ọ́ sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ẹni burúkú Màá rà ọ́ pa dà kúrò lọ́wọ́ àwọn aláìláàánú.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Míkà 4:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Máa yí nínú ìrora, ọmọbìnrin Síónì, kí o sì kérora, Bí obìnrin tó ń rọbí, Torí o máa kúrò ní ìlú, wàá sì lọ gbé ní pápá. 
 
-