Àìsáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà.+ Wọ́n máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì,+Ayọ̀ tí kò lópin sì máa dé wọn ládé.*+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa jẹ́ tiwọn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ sì máa fò lọ.+ Jeremáyà 31:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí Jèhófà máa ra Jékọ́bù pa dà+Á sì gbà á* lọ́wọ́ ẹni tó lágbára jù ú lọ.+ 12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+
11 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà.+ Wọ́n máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì,+Ayọ̀ tí kò lópin sì máa dé wọn ládé.*+ Ìdùnnú àti ayọ̀ máa jẹ́ tiwọn,Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ sì máa fò lọ.+
11 Nítorí Jèhófà máa ra Jékọ́bù pa dà+Á sì gbà á* lọ́wọ́ ẹni tó lágbára jù ú lọ.+ 12 Wọ́n á wá, wọ́n á sì kígbe ayọ̀ ní ibi gíga Síónì+Inú wọn á dùn nítorí oore* Jèhófà,Nítorí ọkà àti wáìnì tuntun+ pẹ̀lú òróró,Nítorí àwọn ọmọ inú agbo ẹran àti ọ̀wọ́ ẹran.+ Wọ́n* á dà bí ọgbà tí a bomi rin dáadáa,+Wọn kò sì ní ráágó mọ́.”+