- 
	                        
            
            2 Àwọn Ọba 3:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ kò ní rí ìjì, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò ní rí òjò; síbẹ̀, omi máa kún àfonífojì yìí,+ ẹ ó sì mu látinú rẹ̀, ẹ̀yin àti àwọn ẹran ọ̀sìn yín pẹ̀lú àwọn ẹran míì tí ẹ ní.”’ 
 
-