-
Sáàmù 57:7-11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ọkàn mi dúró ṣinṣin, Ọlọ́run,+
Ọkàn mi dúró ṣinṣin.
Màá kọrin, màá sì lo ohun ìkọrin.
8 Jí, ìwọ ògo mi.
Jí, ìwọ ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín; àti ìwọ náà, háàpù.
Màá jí ní kùtùkùtù.+
10 Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ga gan-an, ó dé ọ̀run,+
Òtítọ́ rẹ sì ga dé sánmà.
11 Kí a gbé ọ ga ju ọ̀run lọ, ìwọ Ọlọ́run;
Kí ògo rẹ wà lórí gbogbo ayé.+
-