Nọ́ńbà 24:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Édómù sì máa di ohun ìní,+Àní, Séírì+ máa di ohun ìní àwọn ọ̀tá+ rẹ̀,Bí Ísírẹ́lì ṣe ń fi hàn pé òun nígboyà. 2 Sámúẹ́lì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Édómù. Gbogbo Édómù ni ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí, gbogbo àwọn ọmọ Édómù sì di ìránṣẹ́ Dáfídì.+ Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+
18 Édómù sì máa di ohun ìní,+Àní, Séírì+ máa di ohun ìní àwọn ọ̀tá+ rẹ̀,Bí Ísírẹ́lì ṣe ń fi hàn pé òun nígboyà.
14 Ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Édómù. Gbogbo Édómù ni ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí, gbogbo àwọn ọmọ Édómù sì di ìránṣẹ́ Dáfídì.+ Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+