2 Sámúẹ́lì 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọkùnrin oníwàhálà kan wà tó ń jẹ́ Ṣébà,+ ọmọ Bíkíráì láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ni. Ó fun ìwo,+ ó sì sọ pé: “Àwa kò ní ìpín kankan nínú Dáfídì, a kò sì ní ogún kankan nínú ọmọ Jésè.+ Ìwọ Ísírẹ́lì! Kí kálukú pa dà sọ́dọ̀ àwọn ọlọ́run* rẹ̀.”+ 2 Sámúẹ́lì 22:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ikú yí mi ká bí ìgbì òkun;+Àwọn ọkùnrin tí kò ní láárí ya lù mí bí omi.+ 6 Àwọn okùn Isà Òkú* yí mi ká;+Ikú dẹ pańpẹ́ síwájú mi.+ Sáàmù 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí àwọn ajá yí mi ká;+Wọ́n ká mi mọ́ bí ìgbà tí àwọn aṣebi bá káni mọ́,+Wọ́n wà níbi ọwọ́ àti ẹsẹ̀ mi bíi kìnnìún.+
20 Ọkùnrin oníwàhálà kan wà tó ń jẹ́ Ṣébà,+ ọmọ Bíkíráì láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ni. Ó fun ìwo,+ ó sì sọ pé: “Àwa kò ní ìpín kankan nínú Dáfídì, a kò sì ní ogún kankan nínú ọmọ Jésè.+ Ìwọ Ísírẹ́lì! Kí kálukú pa dà sọ́dọ̀ àwọn ọlọ́run* rẹ̀.”+
5 Ikú yí mi ká bí ìgbì òkun;+Àwọn ọkùnrin tí kò ní láárí ya lù mí bí omi.+ 6 Àwọn okùn Isà Òkú* yí mi ká;+Ikú dẹ pańpẹ́ síwájú mi.+
16 Nítorí àwọn ajá yí mi ká;+Wọ́n ká mi mọ́ bí ìgbà tí àwọn aṣebi bá káni mọ́,+Wọ́n wà níbi ọwọ́ àti ẹsẹ̀ mi bíi kìnnìún.+