-
2 Sámúẹ́lì 16:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Bí Ṣíméì ṣe ń ṣépè ló ń sọ pé: “Kúrò níbí, kúrò níbí, ìwọ apààyàn aláìníláárí yìí! 8 Jèhófà ti mú gbogbo ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ ilé Sọ́ọ̀lù wá sórí rẹ, ẹni tí o jọba ní ipò rẹ̀, Jèhófà sì ti fi ìjọba náà lé ọwọ́ Ábúsálómù ọmọ rẹ. Ní báyìí, àjálù ti bá ọ torí pé apààyàn ni ọ́!”+
-