Sáàmù 62:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé e ní gbogbo ìgbà. Ẹ tú ọkàn yín jáde níwájú rẹ̀.+ Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò fún wa.+ (Sélà) Àìsáyà 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+
8 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé e ní gbogbo ìgbà. Ẹ tú ọkàn yín jáde níwájú rẹ̀.+ Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò fún wa.+ (Sélà)
3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+