Sáàmù 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn tó mọ orúkọ rẹ yóò gbẹ́kẹ̀ lé ọ;+Jèhófà, ìwọ kì yóò pa àwọn tó ń wá ọ tì láé.+ Jeremáyà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbùkún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,Ẹni tó fi Jèhófà ṣe ìgbọ́kànlé rẹ̀.+