Sáàmù 99:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 99 Jèhófà ti di Ọba.+ Kí jìnnìjìnnì bá àwọn èèyàn. Ó gúnwà lórí* àwọn kérúbù.+ Kí ayé mì tìtì.