Ẹ́kísódù 15:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+ Àìsáyà 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi. Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán.
2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+ Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+
25 Jèhófà, ìwọ ni Ọlọ́run mi. Mo gbé ọ ga, mo yin orúkọ rẹ,Torí o ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu,+Àwọn ohun tí o pinnu* láti ìgbà àtijọ́,+Nínú òtítọ́,+ nínú ìfọkàntán.