2 Sámúẹ́lì 22:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í sán ààrá láti ọ̀run;+Ẹni Gíga Jù Lọ mú kí a gbọ́ ohùn rẹ̀.+ Sáàmù 29:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 A gbọ́ ohùn Jèhófà lórí omi;Ọlọ́run ológo sán ààrá.+ Jèhófà wà lórí omi púpọ̀.+