Sáàmù 74:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 O la ọ̀nà fún àwọn ìsun omi àti odò;+O mú kí àwọn odò tó ń ṣàn nígbà gbogbo gbẹ táútáú.+ Sáàmù 106:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+ Sáàmù 114:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 114 Nígbà tí Ísírẹ́lì jáde kúrò ní Íjíbítì,+Tí ilé Jékọ́bù jáde kúrò lọ́dọ̀ àwọn tó ń sọ èdè àjèjì, Sáàmù 114:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Òkun rí i, ó sì sá lọ;+Odò Jọ́dánì yíjú pa dà.+ Yorùbá Publications (1987-2025) Jáde Wọlé Yorùbá Fi Ráńṣẹ́ Èyí tí mo fẹ́ràn jù Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania Àdéhùn Nípa Lílò Òfin Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ JW.ORG Wọlé Fi Ráńṣẹ́ Fi Ráńṣẹ́ Lórí Email
9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+ Sáàmù 114:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 114 Nígbà tí Ísírẹ́lì jáde kúrò ní Íjíbítì,+Tí ilé Jékọ́bù jáde kúrò lọ́dọ̀ àwọn tó ń sọ èdè àjèjì, Sáàmù 114:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Òkun rí i, ó sì sá lọ;+Odò Jọ́dánì yíjú pa dà.+
114 Nígbà tí Ísírẹ́lì jáde kúrò ní Íjíbítì,+Tí ilé Jékọ́bù jáde kúrò lọ́dọ̀ àwọn tó ń sọ èdè àjèjì, Sáàmù 114:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Òkun rí i, ó sì sá lọ;+Odò Jọ́dánì yíjú pa dà.+