Sáàmù 97:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+ Sáàmù 101:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mi ò ní gbé ohun tí kò ní láárí* sí iwájú mi. Mo kórìíra iṣẹ́ àwọn tó ń yà kúrò nínú ohun tí ó tọ́;+Mi ò ní bá wọn da nǹkan kan pọ̀.* Òwe 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+ Òwe 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Olódodo kórìíra irọ́,+Àmọ́ ìwà ẹni burúkú ń fa ìtìjú àti àbùkù. Róòmù 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ jẹ́ kí ìfẹ́ yín wà láìsí ẹ̀tàn.*+ Ẹ kórìíra ohun búburú;+ ẹ rọ̀ mọ́ ohun rere.
10 Ẹ̀yin tí ẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà, ẹ kórìíra ohun tó burú.+ Ó ń ṣọ́ ẹ̀mí* àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀;+Ó ń gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́* àwọn ẹni burúkú.+
3 Mi ò ní gbé ohun tí kò ní láárí* sí iwájú mi. Mo kórìíra iṣẹ́ àwọn tó ń yà kúrò nínú ohun tí ó tọ́;+Mi ò ní bá wọn da nǹkan kan pọ̀.*
13 Ìbẹ̀rù Jèhófà ni ìkórìíra ohun búburú.+ Mo kórìíra ìṣefọ́nńté àti ìgbéraga+ àti ọ̀nà ibi àti ọ̀rọ̀ àyídáyidà.+