Sáàmù 19:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Má ṣe jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ hùwà ògbójú;+Má ṣe jẹ́ kí ó jọba lé mi lórí.+ Nígbà náà, màá pé pérépéré,+Ọwọ́ mi á sì mọ́ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.* Róòmù 6:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí náà, ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ máa jọba lọ nínú ara kíkú yín,+ tí ẹ ó fi máa ṣe ìfẹ́ ti ara.
13 Má ṣe jẹ́ kí ìránṣẹ́ rẹ hùwà ògbójú;+Má ṣe jẹ́ kí ó jọba lé mi lórí.+ Nígbà náà, màá pé pérépéré,+Ọwọ́ mi á sì mọ́ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.*