Sáàmù 119:133 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 133 Fi ọ̀rọ̀ rẹ darí ìṣísẹ̀ mi láìséwu;*Kí aburú kankan má ṣe jọba lórí mi.+