2 Sámúẹ́lì 22:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Kí Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi +Àti nítorí mo jẹ́ aláìṣẹ̀ ní iwájú rẹ̀.+ Òwe 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nítorí àwọn ọ̀nà èèyàn wà níwájú Jèhófà;Ó ń ṣàyẹ̀wò gbogbo ipa ọ̀nà rẹ̀.+