Sáàmù 50:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Pè mí ní àkókò wàhálà.+ Màá gbà ọ́ sílẹ̀, wàá sì máa yìn mí lógo.”+ Jónà 2:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìgbà yẹn ni Jónà gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ láti inú ikùn ẹja náà,+ 2 ó sì sọ pé: “Mo ké pe Jèhófà nígbà tí mo wà nínú ìṣòro, ó sì dá mi lóhùn.+ Láti inú* Isà Òkú* ni mo ti kígbe pé kí o ràn mí lọ́wọ́.+ O sì gbọ́ ohùn mi.
2 Ìgbà yẹn ni Jónà gbàdúrà sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ láti inú ikùn ẹja náà,+ 2 ó sì sọ pé: “Mo ké pe Jèhófà nígbà tí mo wà nínú ìṣòro, ó sì dá mi lóhùn.+ Láti inú* Isà Òkú* ni mo ti kígbe pé kí o ràn mí lọ́wọ́.+ O sì gbọ́ ohùn mi.