Diutarónómì 32:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+ Dáníẹ́lì 4:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 “Ní báyìí, èmi Nebukadinésárì ń yin Ọba ọ̀run,+ mò ń gbé e ga, mo sì ń fi ògo fún un, torí òtítọ́ ni gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, ọ̀nà rẹ̀ tọ́,+ ó sì lè rẹ àwọn tó ń gbéra ga wálẹ̀.”+ Ìfihàn 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+
4 Àpáta náà, pípé ni iṣẹ́ ọwọ́+ rẹ̀,Torí ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo+ ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀. Ọlọ́run olóòótọ́,+ tí kì í ṣe ojúsàájú;+Olódodo àti adúróṣinṣin ni.+
37 “Ní báyìí, èmi Nebukadinésárì ń yin Ọba ọ̀run,+ mò ń gbé e ga, mo sì ń fi ògo fún un, torí òtítọ́ ni gbogbo iṣẹ́ rẹ̀, ọ̀nà rẹ̀ tọ́,+ ó sì lè rẹ àwọn tó ń gbéra ga wálẹ̀.”+
3 Wọ́n ń kọ orin Mósè+ ẹrú Ọlọ́run àti orin Ọ̀dọ́ Àgùntàn+ náà, pé: “Jèhófà* Ọlọ́run, Olódùmarè,+ àwọn iṣẹ́ rẹ tóbi, ó sì kàmàmà.+ Òdodo àti òótọ́ ni àwọn ọ̀nà rẹ,+ Ọba ayérayé.+