Dáníẹ́lì 4:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Inú mi dùn láti kéde àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tí Ọlọ́run Gíga Jù Lọ ti ṣe fún mi. 3 Ẹ wo bí àwọn iṣẹ́ àmì rẹ̀ ṣe tóbi tó àti bí àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ṣe lágbára tó! Ìjọba tó wà títí láé ni ìjọba rẹ̀, àkóso rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.+
2 Inú mi dùn láti kéde àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu tí Ọlọ́run Gíga Jù Lọ ti ṣe fún mi. 3 Ẹ wo bí àwọn iṣẹ́ àmì rẹ̀ ṣe tóbi tó àti bí àwọn iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ ṣe lágbára tó! Ìjọba tó wà títí láé ni ìjọba rẹ̀, àkóso rẹ̀ sì wà láti ìran dé ìran.+