Sáàmù 86:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà, kò sí èyí tó dà bí rẹ nínú àwọn ọlọ́run,+Kò sí iṣẹ́ kankan tó dà bíi tìrẹ.+ Àìsáyà 45:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì. Kò sí Ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Màá fún ọ lókun,* bó ò tiẹ̀ mọ̀ mí,
5 Èmi ni Jèhófà, kò sí ẹlòmíì. Kò sí Ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Màá fún ọ lókun,* bó ò tiẹ̀ mọ̀ mí,