- 
	                        
            
            1 Kọ́ríńtì 8:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn tí à ń pè ní ọlọ́run wà, ì báà jẹ́ ní ọ̀run tàbí ní ayé,+ bí ọ̀pọ̀ “ọlọ́run” àti ọ̀pọ̀ “olúwa” ṣe wà, 6 ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà,+ Baba,+ ọ̀dọ̀ ẹni tí ohun gbogbo ti wá, tí àwa náà sì wà fún un;+ Olúwa kan ló wà, Jésù Kristi, ipasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo fi wà,+ tí àwa náà sì wà nípasẹ̀ rẹ̀. 
 
-