Jẹ́nẹ́sísì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. Sáàmù 24:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jèhófà ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀,+Ilẹ̀ tó ń méso jáde àti àwọn tó ń gbé orí rẹ̀. 2 Nítorí ó ti fìdí rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkun+Ó sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ sórí àwọn odò.
9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
24 Jèhófà ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀,+Ilẹ̀ tó ń méso jáde àti àwọn tó ń gbé orí rẹ̀. 2 Nítorí ó ti fìdí rẹ̀ sọlẹ̀ sórí òkun+Ó sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ sórí àwọn odò.