- 
	                        
            
            Sáàmù 36:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Má ṣe jẹ́ kí ẹsẹ̀ àwọn agbéraga tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ Tàbí kí ọwọ́ àwọn ẹni burúkú lé mi dà nù. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 71:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Ọlọ́run mi, gbà mí lọ́wọ́ ẹni burúkú,+ Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tó ń ni èèyàn lára láìtọ́. 
 
-