2 Sámúẹ́lì 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó ta àwọn ọfà+ rẹ̀, ó sì tú wọn ká;Mànàmáná kọ, ó sì kó wọn sínú ìdàrúdàpọ̀.+