- 
	                        
            
            Sáàmù 33:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Ẹ kọ orin tuntun sí i;+ Ẹ fi ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín dárà, bí ẹ ti ń kígbe ayọ̀. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 40:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Ó wá fi orin tuntun sí mi lẹ́nu,+ Ìyìn sí Ọlọ́run wa. Ọ̀pọ̀ èèyàn á rí nǹkan yìí, ẹ̀rù Ọlọ́run á bà wọ́n, Wọ́n á sì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà. 
 
-