2 Sámúẹ́lì 5:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ gbéjà ko àwọn Filísínì? Ṣé wàá fi wọ́n lé mi lọ́wọ́?” Ni Jèhófà bá sọ fún Dáfídì pé: “Lọ, torí ó dájú pé màá fi àwọn Filísínì lé ọ lọ́wọ́.”+ Sáàmù 18:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+
19 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lọ gbéjà ko àwọn Filísínì? Ṣé wàá fi wọ́n lé mi lọ́wọ́?” Ni Jèhófà bá sọ fún Dáfídì pé: “Lọ, torí ó dájú pé màá fi àwọn Filísínì lé ọ lọ́wọ́.”+
50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+