2 Sámúẹ́lì 22:50, 51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ìdí nìyẹn tí màá fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà, láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+Màá sì fi orin yin*+ orúkọ rẹ: 51 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.”+ 1 Kíróníkà 16:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ kọrin sí i, ẹ fi orin yìn ín,*+Ẹ máa ronú lórí* gbogbo àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀.+ Róòmù 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 kí àwọn orílẹ̀-èdè sì lè yin Ọlọ́run lógo nítorí àánú rẹ̀.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ìdí nìyẹn tí màá fi yìn ọ́ ní gbangba láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí màá sì fi orin yin orúkọ rẹ.”+
50 Ìdí nìyẹn tí màá fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà, láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+Màá sì fi orin yin*+ orúkọ rẹ: 51 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.”+
9 kí àwọn orílẹ̀-èdè sì lè yin Ọlọ́run lógo nítorí àánú rẹ̀.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ìdí nìyẹn tí màá fi yìn ọ́ ní gbangba láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí màá sì fi orin yin orúkọ rẹ.”+